2 Chronicles 8:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó tún àwọn ìlú tí Huramu ọba, fún un kọ́, ó sì fi àwọn ọmọ Israẹli sibẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni Solomoni kọ́ ilu wọnni ti Huramu fi fun Solomoni, o si mu ki awọn ọmọ Israeli ki o ma gbe ibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sólómónì tún ìlú tí Hírámù ti fi fún un kọ́, ó sì kó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ níbẹ̀ kí wọn kí ó lè máa gbé nínú ibẹ̀.