2 Chronicles 8:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó lọ gbógun ti ìlú Hamati ati Soba, ó sì ṣẹgun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Solomoni si lọ si Hamati-Soba, o si bori rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Sólómónì lọ sí Hámátì Sóbà ó sì borí rẹ̀.