2 Chronicles 8:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
bẹ́ẹ̀ sì ni ìlú Baalati ati gbogbo ìlú tí wọn ń kó ìṣúra pamọ́ sí, ati àwọn ìlú tí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ wà, ati ìlú fún àwọn ẹlẹ́ṣin, ati gbogbo ohun tí ó pinnu lọ́kàn rẹ̀ láti kọ́ ní Jerusalẹmu, ati ní Lẹbanoni, ati ní gbogbo ibi tí ìjọba rẹ̀ dé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Baalati, ati gbogbo ilu iṣura ti Solomoni ni, ati gbogbo ilu kẹkẹ́, ati ilu ẹlẹṣin, ati gbogbo eyiti Solomoni fẹ lati kọ́ ni Jerusalemu, ati ni Lebanoni ati ni gbogbo ilẹ ijọba rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti gẹ́gẹ́ bí Bálátì àti gbogbo ìlú Ìṣúra, àti gbogbo ìlú fún kẹ̀kẹ́ rẹ̀ àti fún àwọn ẹsin rẹ̀ ohunkóhun tí ó bá yẹ ní kókó ní Jérúsálẹ́mù, ní Lẹ́bánónì àti ní gbogbo àyíká agbégbé tí ó ń darí.