2 Chronicles 8:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n kù ní ilẹ̀ náà lára àwọn ará Hiti, ati àwọn ará Amori, àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi ati àwọn ará Jebusi, tí wọn kì í ṣe ọmọ Israẹli,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn enia ti o kù ninu awọn ara Hitti, ati awọn Amori, ati awọn Peresi, ati awọn Hifi ati awọn Jebusi, ti kì iṣe ti inu ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ènìyàn tí ó kúrò láti ara àwọn ará Hítì, ará Ámórò, ará Pérísì, ará Hífì àti ará Jébúsì (Àwọn ènìyàn wọ̀nyí wọn kì í ṣe àwọn ará Ísírẹ́lì),