2 Chronicles 9:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tún fi wúrà tí a fi òòlù lù ṣe ọọdunrun (300) apata kéékèèké. Ìwọ̀n wúrà tí ó lò fún ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọọdunrun (300) ṣekeli. Ọba kó wọn sí ààfin Igbó Lẹbanoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọdunrun apata wura lilù li o si ṣe; apata kan gbà ọ̃dunrun ṣekeli wura: ọba si fi wọn sinu ile igbo Lebanoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ti ṣe ọ̀ọ́dúnrún (300) kékeré ṣékélì tí a fi òlù lù wúrà, pẹ̀lú ọ̀ọ́dúnrún (3,000) sékélì wúrà nínú àpáta kọ̀kan. Ọba sì kó wọn sínú ilé ti igbó Lébánónì.