2 Chronicles 9:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba fi eyín erin ṣe ìtẹ́ ńlá kan, ó sì yọ́ ojúlówó wúrà bò ó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si ṣe itẹ́ ehin-erin nla kan, o si fi wura daradara bò o.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ọba sì ṣe ìtẹ́ pẹ̀lú èyín erin ńlá kan ó sì fi wúrà tó mọ́ bò ó.