2 Chronicles 9:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Solomoni ọba ní ọrọ̀ ati ọgbọ́n ju gbogbo àwọn ọba yòókù lọ lórí ilẹ̀ ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Solomoni ọba si tobi jù gbogbo ọba aiye lọ li ọrọ̀ ati li ọgbọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba Solómónì sì tóbi nínú ọlá ńlá àti ọgbọ́n ju gbogbo àwọn ọba tí ó kù lórí ilẹ̀ ayé lọ.