2 Chronicles 9:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn ni wọ́n ń wá láti gbọ́ ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tí Ọlọrun fún un. Fún ọpọlọpọ ọdún ni
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ọba aiye si nwá oju Solomoni, lati gbọ́ ọgbọ́n rẹ̀ ti Ọlọrun ti fi si i li ọkàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọba ayé ń wá ojú rere lọ́dọ̀ Sólómónì láti gbọ́n ọgbọ́n tí Ọlọ́run ti fi sínú ọkàn rẹ̀.