2 Corinthians 11:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo fẹ́rẹ̀ jẹ àwọn ìjọ mìíràn run, tí mò ń gba owó lọ́wọ́ wọn láti ṣe iṣẹ́ fun yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ja ijọ miran li ole, mo ngbà owo ki emi ki o le sìn nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmí ń ja ìjọ mìíràn ni olè nípa gbigba ìpèsè owó ki èmi bà á lè sìn yín.