2 Corinthians 2:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, mo pinnu pé n kò tún fẹ́ kí wíwá tí mo bá wá sọ́dọ̀ yín jẹ́ ti ìbànújẹ́ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ṢUGBỌN mo ti pinnu eyi ninu emi tikarami pe, emi kì yio tun fi ibinujẹ tọ̀ nyin wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà mo tí pínnú nínú ara mí pé, èmi kì yóò tún fí ìbànújẹ́ tọ̀ yin wá.