2 Corinthians 3:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gẹ́gẹ́ bí Ìwé Mímọ́ ti sọ nípa Mose, “Nígbàkúùgbà tí ó bá yipada sí Oluwa, a mú aṣọ kúrò lójú.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati on o ba yipada si Oluwa, a o mu iboju na kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nígbà ti òun bá yípadà sí Olúwa, a ó mú ìbòjú náà kúrò.