2 Corinthians 8:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ète wa dára lójú Oluwa, ó sì dára lójú àwọn eniyan pẹlu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awa ngbero ohun rere, kì iṣe niwaju Oluwa nikan, ṣugbọn niwaju enia pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwa ń gbérò ohun rere, kì í ṣe níwájú Olúwa nìkan, ṣùgbọ́n níwájú ènìyàn pẹ̀lú.