2 Corinthians 8:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A tún rán arakunrin wa tí a ti dánwò ní oríṣìíríṣìí ọ̀nà ní ti ìtara rẹ̀ pé kí ó bá wọn wá. Nisinsinyii ó túbọ̀ ní ìtara pupọ nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé yín pupọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awa si ti rán arakunrin wa pẹlu wọn, ẹniti awa ri daju nigba pipọ pe o ni itara ninu ohun pipọ, ṣugbọn nisisiyi ni itara rẹ̀ tubọ pọ si i nipa igbẹkẹle nla ti o ni si nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwa sì ti rán arákùnrin wa pẹ̀lú wọn, ẹni tí àwa rí dájú nígbà púpọ̀ pé ó ní ìtara nínú ohun púpọ̀, ṣùgbọ́n ní isínsnyìí ni ìtara rẹ̀ túbọ pọ̀ sí i nípa ìfọkàntàn ńlá tí ó ní sí yín.