2 Kings 10:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní, “Tẹ̀lé mi, kí o wá wo ìtara mi fún OLUWA.” Wọ́n sì jọ gun kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ lọ sí Samaria.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si wipe, Ba mi lọ ki o si wò itara mi fun Oluwa. Bẹ̃ni nwọn mu u gùn kẹkẹ́ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jéhù wí pé, “Wá pẹ̀lú ù mi; kí o sì rí ìtara mi fún OLÚWA.” Nígbà náà ó jẹ́ kí ó gun kẹ̀kẹ́ rẹ̀.