2 Kings 10:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n kó gbogbo àwọn ère tí wọ́n wà níbẹ̀ jáde, wọ́n sì sun wọ́n níná.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si kó awọn ere lati ile Baali jade, nwọn si sun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gbé òkúta bíbọ náà jáde láti inú ilé tí a kọ́ fún òrìṣà Báálì, wọ́n sì jó o.