2 Kings 11:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jehoiada alufaa mú kí Joaṣi ọba ati àwọn eniyan dá majẹmu pẹlu OLUWA pé àwọn yóo jẹ́ tirẹ̀; ó sì tún mú kí àwọn eniyan náà bá ọba dá majẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jehoiada si da majẹmu lãrin Oluwa ati ọba ati awọn enia, pe, ki nwọn ki o mã ṣe enia Oluwa; ati lãrin ọba pẹlu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jéhóíádà dá májẹ̀mú láàrin OLÚWA àti ọba àti àwọn ènìyàn tí yóò jẹ́ ènìyàn OLÚWA. Ó dá májẹ̀mú láàrin ọba àti àwọn ènìyàn pẹ̀lú.