2 Kings 11:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn eniyan kún fún ayọ̀, gbogbo ìlú sì ní alaafia lẹ́yìn tí wọ́n ti fi idà pa Atalaya ní ààfin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn enia ilẹ na si yọ̀, ilu na si tòro; nwọn si fi idà pa Ataliah li eti ile ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà sì yọ̀, pẹ̀lú ìlú ńlá náà sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorí a pa Ataláyà pẹ̀lú idà náà ní ààfin.