2 Kings 11:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọmọ ọdún meje ni Joaṣi nígbà tí ó jọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹni ọdun meje ni Jehoaṣi nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóásì jẹ́ ọmọ ọdún méje nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ ìjọba rẹ̀.