2 Kings 11:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joaṣi wà ní ìpamọ́ ninu ilé OLUWA fún ọdún mẹfa, Atalaya sì ń jọba lórí ilẹ̀ Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si pa a mọ́ pẹlu rẹ̀ ni ile Oluwa li ọdun mẹfa. Ataliah si jọba lori ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wà ní ìpamọ́ pẹ̀lú olùtọ́jú ní ilé tí a kọ́ fún OLÚWA fún ọdún mẹ́fà nígbà tí Ataláyà fi jọba lórí ilẹ̀ náà.