2 Kings 12:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ ó ṣe ohun tí ó tọ́ lójú OLUWA nítorí pé Jehoiada alufaa ń tọ́ ọ sọ́nà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jehoaṣi si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa li ọjọ rẹ̀ gbogbo ninu eyiti Jehoiada alufa nkọ́ ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóásì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú OLÚWA ní gbogbo ọdún tí Jéhóíádà àlùfáà fi àsẹ fún un.