2 Kings 13:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Eliṣa bá sọ fún un pé kí ó mú ọrun ati ọfà, ó sì mú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eliṣa si wi fun u pe, Mu ọrun pẹlu ọfà: on si mu ọrun ati ọfà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èlíṣà wí pé, “Mú ọrun kan àti àwọn ọfà,” ó sì ṣe bẹ́ẹ̀.