2 Kings 16:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pẹpẹ idẹ tí a ti yà sọ́tọ̀ fún OLUWA wà ní ààrin pẹpẹ tirẹ̀ ati ilé OLUWA. Nítorí náà, Ahasi gbé pẹpẹ idẹ náà sí apá òkè pẹpẹ tirẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o mu pẹpẹ idẹ ti o wà niwaju Oluwa kuro lati iwaju ile na, lati agbedemeji pẹpẹ na, ati ile Oluwa, o si fi i si apa ariwa pẹpẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó mú pẹpẹ idẹ tí ó wà níwájú OLÚWA kúrò láti iwájú ilé náà, láti àárin méjì pẹpẹ náà, àti ilé OLÚWA, ó sì fi í sí apá àríwá pẹpẹ náà.