2 Kings 17:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn eniyan náà kò gbọ́, wọ́n sì ń tẹ̀lé ìwà àtijọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kò si gbọ́, ṣugbọn nwọn ṣe bi iṣe wọn atijọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn kò ní gbọ́, bẹ́ẹ̀ ni, wọ́n sì ń ṣe iṣẹ́ wọ́n ti àtijọ́.