2 Kings 18:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọdún kẹrinla tí Hesekaya jọba ní Juda, ni Senakeribu, ọba Asiria, gbógun ti àwọn ìlú olódi Juda, ó sì ṣẹgun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọdun kẹrinla Hesekiah ọba, ni Sennakeribu ọba Assiria gòke wá si gbogbo awọn ilu olodi Juda, o si kó wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọdún kẹrìnlá tí Heṣekáyà jọba, Ṣenakérúbù ọba Ásíríà kọlu gbogbo ìlú olódi ti Júdà ó sì pa wọ́n run.