2 Kings 18:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Hesekaya bá kó gbogbo fadaka tí ó wà ninu ilé OLUWA ati ti inú ilé ìṣúra tí ó wà ní ààfin ranṣẹ sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Hesekiah si fun u ni gbogbo fadakà ti a ri ni ile Oluwa, ati ninu iṣura ile ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Heṣekáyà fún un ní gbogbo fàdákà tí wọ́n rí nínú ilé OLÚWA àti nínú ilé ìṣúra ọba.