2 Kings 18:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ó mú ki ẹ gbẹ́kẹ̀lé OLUWA kí ó máa sọ pé OLUWA yóo gbà yín sílẹ̀, ati pé kò ní jẹ́ kí ogun Asiria kó ìlú yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ máṣe jẹ ki Hesekiah mu nyin gbẹkẹle Oluwa, wipe, Ni gbigbà Oluwa yio gbà wa, a kì yio si fi ilu yi le ọba Assiria lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má se jẹ́ kí Héṣékíáyà tì ọ́ láti gbàgbọ́ nínú OLÚWA nípa sísọ pé, ‘OLÚWA yóò gbà wá nítòótọ́; ìlú yìí ni wọn kò ní fi lé ọba ìlú Ásíríà lọ́wọ́.’