2 Kings 18:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣé ọlọrun àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn gbà wọ́n lọ́wọ́ ọba Asiria?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkan ninu awọn oriṣa awọn orilẹ-ède ti igbà ilẹ rẹ̀ kuro lọwọ ọba Assiria ri bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣé òrìṣà àwọn orílẹ̀ èdè kankan ti gba ilé rẹ lọ́wọ́ àwọn ọba Ásíríà?