2 Kings 18:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni Eliakimu, tí ń ṣe àkóso ààfin ati Ṣebina, akọ̀wé ọba, ati Joa, tí ń ṣe àkóso ìwé ìrántí fa aṣọ wọn ya láti fi ìbànújẹ́ wọn hàn, wọ́n sì lọ sọ ohun tí olórí ogun náà wí fun ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Eliakimu ọmọ Hilkiah ti iṣe olori ile, ati Ṣebna akọwe, ati Joa ọmọ Asafu akọwe-iranti wá sọdọ Hesekiah, ti awọn, ti aṣọ wọn ni fifàya, nwọn si sọ ọ̀rọ Rabṣake fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Élíákímù ọmọ Hílíkíyà olùtọ́jú ààfin, Séríbù akọ̀wé àti Jóà ọmọ Ásáfù akọ̀wé ránsẹ́ lọ sí ọ̀dọ̀ Héṣékíáyà, pẹ̀lú aṣọ wọn yíya, ó sì wí fún un ohun tí olùdárí pápá ti sọ.