2 Kings 18:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó jẹ́ olóòótọ́ sí OLUWA, kò yapa kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, ṣugbọn ó fi tọkàntọkàn pa àwọn òfin tí OLUWA fún Mose mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti o faramọ Oluwa, kò si lọ kuro lẹhin rẹ̀, ṣugbọn o pa ofin rẹ̀ wọnni mọ, ti Oluwa ti pa li aṣẹ fun Mose.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sún mọ́ OLÚWA, kò sì dẹ́kun láti tì í lẹ́yìn: ó sì pa òfin OLÚWA mọ́ tí ó ti fi fún Mósè.