2 Kings 19:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo gbẹ́ kànga ní ilẹ̀ àjèjì, mo sì mu omi rẹ̀; ẹsẹ̀ àwọn jagunjagun mi ni ó sì gbẹ́ àwọn odò Ijipti.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti wà kànga, emi si ti mu ajèji omi, atẹlẹsẹ̀ mi li emi si ti fi gbẹ gbogbo odò Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo ti gbẹ́ kàǹga ní ilẹ̀ àjèjì Mo sì mu omi níbẹ̀. Pẹ̀lú àtẹ́lẹṣẹ̀ mi, Èmi ti gbẹ́ gbogbo omi odò tí ó wà ní Éjíbítì.”