2 Kings 19:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan yóo là ní Jerusalẹmu, àwọn eniyan yóo sì ṣẹ́kù ni Òkè Sioni, nítorí pé ìtara ni OLUWA yóo fi ṣe é.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori lati Jerusalemu li awọn iyokù yio jade lọ, ati awọn ti o salà lati oke Sioni jade: itara Oluwa awọn ọmọ-ogun ni yio ṣe eyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti inú Jérúsálẹ́mù ní àwọn ìyókù yóò ti wá àti láti orí òkè Ṣíónì ni ọ̀pọ̀ àwọn tí ó ṣá àsálà. Ìtara OLÚWA àwọn ọmọ ogun yóò ṣe èyí.