2 Kings 19:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n jíṣẹ́ ọba fún Aisaya tán,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li awọn iranṣẹ Hesekiah ọba wá sọdọ Isaiah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ìránṣẹ́ ọba Héṣékáyà lọ sí ọ̀dọ̀ Àìṣáyà,