2 Kings 20:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn yóo kó ninu àwọn ọmọ rẹ lọ fi ṣe ìwẹ̀fà ní ààfin ọba Babiloni.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ rẹ ọkunrin ti yio ti inu rẹ jade wá, ti iwọ o bi, ni nwọn o kó lọ; nwọn o si mã ṣe iwẹ̀fa li ãfin ọba Babeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti díẹ̀ nínú àwọn ilé rẹ, ẹran ara rẹ àti ẹ̀jẹ̀, tí wọn yóò bí fún ọ, ni wọn yóò kó lọ, wọn yóò sì di ìwọ̀fà ní ààfin ọba Bábílónì.”