2 Kings 20:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Hesekaya kú, wọ́n sì sin ín sinu ibojì àwọn baba rẹ̀; Manase ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Hesekiah si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀: Manasse ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Heṣekáyà sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀: Mánásè ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.