2 Kings 21:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Manase ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA nítorí pé ó tẹ̀lé ìwà ìríra àwọn eniyan ilẹ̀ náà, tí OLUWA lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe eyiti o buru li oju Oluwa, bi iṣe-irira ti awọn keferi, ti Oluwa tì jade niwaju awọn ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ṣe búburú ní ojú OLÚWA, ó sì tẹ̀lé iṣẹ́ ìríra tí àwọn orílẹ̀ èdè tí OLÚWA lé jáde níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.