2 Kings 21:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ oriṣa sinu ilé OLUWA, níbi tí OLUWA ti pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli láti máa sin òun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si tẹ́ pẹpẹ ni ile Oluwa, eyiti Oluwa ti sọ pe, Ni Jerusalemu li emi o fi orukọ mi si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì kọ́ pẹpẹ nínú ilé tí a kọ́ fún OLÚWA, èyí tí OLÚWA ti sọ pé, “Ní Jérúsálẹ́mù ni èmi yóò kọ orúkọ mi sí.”