2 Kings 23:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Josaya bá pe ìpàdé gbogbo àwọn olórí Juda ati Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌBA si ranṣẹ, nwọn si pè gbogbo awọn àgba Juda ati Jerusalemu jọ sọdọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ọba pe gbogbo àwọn àgbààgbà Júdà àti Jérúsálẹ́mù jọ.