2 Kings 23:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òun náà ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, ó tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si ṣe eyiti o buru li oju Oluwa, gẹgẹ bi gbogbo eyiti awọn baba rẹ̀ ti ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ṣe búburú lójú OLÚWA gẹ́gẹ́ bí baba a rẹ̀ ti ṣe.