2 Kings 24:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní àkókò náà ni àwọn ọmọ ogun Nebukadinesari, ọba Babiloni, lọ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dó tì í.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li akokò na, awọn iranṣẹ Nebukadnessari ọba Babeli gbé ogun wá si Jerusalemu, a si dotì ilu na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àkókò náà àwọn ìjòyè Nebukadinéṣárì ọba Bábílónì wá sílẹ̀ Jérúsálẹ́mù wọ́n sì gbé dófì kalẹ̀ fún un,