2 Kings 24:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní àkókò tí wọ́n dó ti ìlú náà ni Nebukadinesari ọba Babiloni lọ sibẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nebukadnessari ọba Babeli si de si ilu na, nigbati awọn iranṣẹ rẹ̀ si dotì i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nebukadinéṣárì fúnrarẹ̀ wá sókè sí ìlú nígbà tí àwọn ìjòyè fi ogun dótì í.