2 Kings 25:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nebusaradani kó àwọn tí wọ́n kù láàrin ìlú ati àwọn tí wọ́n sá tọ ọba Babiloni lọ, pẹlu ogunlọ́gọ̀ àwọn yòókù lọ sí ìgbèkùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iyokù awọn enia ti o kù ni ilu ati awọn isansa ti o ya tọ̀ ọba, Babeli lọ, pẹlu ọ̀pọlọpọ enia ti o kù, ni Nebusaradani olori ẹ̀ṣọ kó lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nebukadinésárí olórí ẹ̀ṣọ́ Kó lọ sí ìgbékùn gbogbo ènìyàn tí ó kù ní ìlú, àti àwọn Ísánsà àti àwọn tí ó ti lo sí ọ̀dọ̀ ọba Bábílón.