2 Kings 25:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ó fi díẹ̀ ninu àwọn talaka sílẹ̀ láti máa tọ́jú ọgbà àjàrà ati láti máa dáko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn olori ẹ̀ṣọ fi awọn talakà ilẹ na silẹ, lati mã ṣe alabojuto àjara ati lati mã ṣe aroko.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n olórí ẹ̀sọ́ fí àwọn talákà ènìyàn ilẹ̀ náà sílẹ̀ láti ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àti orí pápá.