2 Kings 25:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dó ti ìlú náà títí di ọdún kọkanla ìjọba Sedekaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si dotì ilu na titi di ọdun ikọkanla Sedekiah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìlú náà sì wà ní ìhámọ́ lábẹ́ ìdọ̀tí títí di ọdún kọkànlá ti ọba Ṣédékíáyà.