2 Kings 3:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní, “Ẹ pe akọrin kan wá.” Bí akọrin náà ti ń kọrin ni agbára OLUWA bà lé Eliṣa,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹ mu akọrin kan fun mi wá nisisiyi. O si ṣe, nigbati akọrin na nkọrin, ọwọ Oluwa si bà le e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Nísinsìn yìí mú wá fún mi ohun èlò orin olókun.” Nígbà tí akọrin náà n kọrin, ọwọ́ OLÚWA wá sórí Èlíṣà.