2 Kings 3:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nǹkan kékeré ni èyí jẹ́ níwájú OLUWA, yóo fun yín ní agbára láti borí àwọn ará Moabu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun kikini si li eyi loju Oluwa: on o fi awọn ara Moabu le nyin lọwọ pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí jẹ́ ohun tí kò lágbára níwájú OLÚWA, yóò sì fi Móábù lé e yín lọ́wọ́ pẹ̀lú.