2 Kings 3:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ọba Moabu rí i pé ogun náà le pupọ, ó mú ẹẹdẹgbẹrin (700) ọkunrin tí wọ́n ń lo idà, ó gbìyànjú láti la ààrin ogun kọjá níwájú ọba Edomu, ṣugbọn kò ṣeéṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ọba Moabu ri i pe ogun na le jù fun on, o mu ẹ̃dẹgbẹrin ọkunrin ti o fà idà yọ pẹlu rẹ̀, lati là ogun ja si ọdọ ọba Edomu: ṣugbọn nwọn kò le ṣe e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ọba Móábù rí i wí pé ogun náà le ju ti òun lọ, ó mú idà pẹ̀lú ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ọkùnrin (700) onídà láti jà pẹ̀lú ọba Édómù, ṣùgbọ́n wọn kò yege.