2 Kings 6:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn jọ lọ, nígbà tí wọ́n dé etí odò Jọdani, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí gé igi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li o ba wọn lọ. Nigbati nwọn si de Jordani, nwọn ké igi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì lọ pẹ̀lú wọn. Wọ́n sì lọ sí Jọ́dánì wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ní gé igi