2 Kings 7:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn aṣọ́nà bá sọ fún àwọn tí wọ́n wà ní ààfin ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikan si pè awọn onibodè; nwọn si sọ ninu ile ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn aṣọ́bodè náà pariwo ìròyìn náà, wọ́n sì sọ nínú ààfin.