2 Kings 7:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó sì rí bẹ́ẹ̀ fún un, nítorí àwọn eniyan tẹ ọ̀gágun náà pa ní ẹnubodè ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li o si ri fun u: nitori awọn enia tẹ̀ ẹ mọlẹ ni ẹnu bodè, o si kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ó sì rí fún un gẹ́lẹ́, nítorí tí àwọn ènìyàn tẹ̀ẹ́ mọ́lẹ̀ ní ẹnu ibodè, ó sì kú.