2 Peter 2:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó jẹ́ pé àwọn angẹli tí wọ́n ní agbára ati ipá ju eniyan lọ, kò jẹ́ sọ ìsọkúsọ sí wọn nígbà tí wọn bá ń mú wọn lọ fún ìdájọ́ Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹni awọn angẹli bi nwọn ti pọ̀ ni agbara ati ipá tõ nì, nwọn kò dá wọn lẹjọ ẹ̀gan niwaju Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ańgẹ́lì bí wọ́n ti pọ̀ ní agbára àti ipá tó ò ní wọn kò dá wọ́n lẹ́jọ́ ẹ̀gàn níwájú Olúwa.